• About
  • Radio
  • Gallery
  • Contact
Afronews
Advertisement
  • Home
  • News
  • Academics
  • Infotech
  • Entertainment
    • Fashion
    • Sports
  • Personality & Interview
    • Opinions
    • Weekly Insights
  • Advert
  • Afrograms & its community
    • Alumni Corner
    • Features
    • Meetings
    • Plublications
  • Health
No Result
View All Result
  • Home
  • News
  • Academics
  • Infotech
  • Entertainment
    • Fashion
    • Sports
  • Personality & Interview
    • Opinions
    • Weekly Insights
  • Advert
  • Afrograms & its community
    • Alumni Corner
    • Features
    • Meetings
    • Plublications
  • Health
No Result
View All Result
afronews.ng
No Result
View All Result
Home News

AWON AKEKO JADE DA AWON AKEKO ATI OLUKO AFRICAN CHURCH GRAMMAR SCHOOL

Olawale Olamide by Olawale Olamide
March 18, 2026
in News
67
0
SHARES
Share on FacebookShare on Twitter

AWON AKEKO JADE DA AWON AKEKO ATI OLUKO AFRICAN CHURCH GRAMMAR SCHOOL LOLA – Olukotan : Sanusi Aishat

Ni dede ọjọ kẹfa, oṣu keji, ọdun ti a wa yii. Ni awọn akẹkọọ ti won  jade ile-ẹkọ African Church Grammar School (Snr), wa si ile-ẹkọ naa, lati wa san pada fun ile-ẹkọ naa gẹgẹ bi wọn ti n ṣe nipa ṣiṣe  koriya fun awọn akẹkọọ ti o ṣe daadaa julọ ninu ẹkọ wọn ati ihuwasi wọn ninu ile-ẹkọ naa.

Ati lati fi ṣe iwuri fun wọn lati maa tẹsiwaju ninu ẹkọ wọn, nitori ọpọlọpọ ninu awọn akẹkọọ gba pe ẹkọ ko wulo, nitori idi eyi, awọn akẹkọọ ti won  jade yii n jẹ ki o fi ye wa wi pe kii ṣe ọjọ ọla nikan ni ẹkọ ti daa o je; oun anfaani fun wa nitori awọn miiran ti wọn mọ iyi ẹkọ o wuu wọn lati kawe ṣugbọn anfaani ni ko si. Nitori eyi Aare gbogbogbo fun awon akeko jade naa , oni-imo ofin Bola Shittu,  wọn gba awon akeko  niyanju lati gbajumọ ẹkọ won  nitori o ni iwulo gidigidi.

Nitori idi eyi ni wọn ṣe wa fun awọn akẹkọọ ti o ṣe daadaa julọ ninu ẹkọ won ni ebun owo ati aami idalola , ki awọn akẹkọọ yooku na le mọ wi pe ẹkọ jẹ ohun iyi ti o si yẹ ki a gbajumọ gẹgẹ bi akẹkọọ. Awọn akẹkọọ jade naa si tẹsiwaju lati yẹ awọn olukọ kankan si, nipa fifun wọn ni ẹbun owo bi wọn tin ṣe fun awọn akẹkọọ. Ki wọn le tun bọ maa ran awọn akẹkọọ lọwọ, nitori iṣẹ gidigidi ni wọn n ṣe lori awọn akẹkọọ ki wọn le yege, kii tun wa ṣe nipa ẹkọ nikan ni awọn olukọ n ba ran awọn akẹkọọ lọwọ, wọn tun tọ wọn bi ọmọ bibi inu wọn ni, wọn kọ wọn ni ohun ti o tọ, ati ohun ti oye fun omoluabi lawujo .

Ati awọn ohun ti a ko le fi ẹnu tabi gege wa kọ tan, nitori eniyan pataki ni wọn lawujọ awa eniyan. Nitori iru eniyan ti wọn jẹ ni awọn akẹkọọ jade naa fi ẹmi imoore han si wọn, ki wọn tun le maa ṣe ju bẹe  lọ. Apapọ ẹbun owo ti awọn akẹkọọ jade naa fun awọn akẹkọọ ati olukọ naa n lọ bi ọpọlọpọ miliọnu naira.

Wọn si ni diẹ lara awọn akẹkọọ ti o jẹ ninu anfaani ẹbun owo naa ni;

Arabinrin Folarin Faridat ti o jẹ ileeko akeko agba (ss3) kilasii keeta , ti o jẹ oun ni ẹbun rẹ pọ ju, ti ẹbun rẹ si ju mẹwaa loo, ti o si fi han wa pe dajudaju akẹkọọ na mu ẹkọ rẹ ni okunkundun.

Arabinrin Sanusi Aishat ti n ṣe akẹkọọ ileeko agba, kilaasi keji (ss2), ti o si gba ẹbun lori ede Yoruba. Arabinrin Abidoye Oyinlọla akẹkọọ ileeko agba, kilaasi keji(ss2), ti o si gba ẹbun lori litireso ede Gẹẹsi. Arakunrin Rabo Joshua akẹkọọ ileeko agba,  kilaasi keji(ss2)  ti oun naa si gba ẹbun lori ẹkọ iṣiro. Ati bẹẹ bẹẹ lọ ti a ko le kọ tan. Ninu awọn olukọ ti o jẹ anfaani ẹbun naa ni; Olukọ Abiodun ti o kọ ona aworan ti o jẹ wi pe awọn akẹkọọ ileeko agba ni wọn n kọ. Olukọ Oṣinẹyẹ ti o kọ ede Faransé ti o n kọ awọn akẹkọọ ileeko kekere  (junior school). ati ohun iwuri

Eyi a jẹ koriya fun awon akẹkọọ ati awọn olukọ to ku, ki wọn fi tokantọkan ati ara  ṣiṣẹ wọn.

From Afronews
visit Our Website for more Stories at www.afronews.ng
Previous Post

Thursday 19th and 20th March Are Public Holidays

Next Post

Title for the sport – TEACHERS WEAR OFF BOREDOM WITH SPORT

Olawale Olamide

Olawale Olamide

Next Post
Title for the sport –  TEACHERS WEAR OFF BOREDOM WITH SPORT

Title for the sport - TEACHERS WEAR OFF BOREDOM WITH SPORT

Comments 67

  1. Oyebola Fathia says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
  2. AKANNI SEMIAT OLUWAFEYIFUNMI says:
    8 months ago

    Awesome

    Reply
  3. Eleko samuel says:
    8 months ago

    That’s great

    Reply
  4. Sowunmi Paul olumide says:
    8 months ago

    Great job 👍⭐

    Reply
  5. Odesesan Aliyah says:
    8 months ago

    Well done

    Reply
  6. Dada niniola says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  7. David says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
    • Ajayi Feyikemi Faheez says:
      8 months ago

      That great

      Reply
  8. David says:
    8 months ago

    Up school

    Reply
  9. David says:
    8 months ago

    Wonderful 👏

    Reply
  10. Rapheal says:
    8 months ago

    Good

    Reply
  11. David says:
    8 months ago

    Up Afro grams

    Reply
  12. Akinola sulaimon says:
    8 months ago

    God bless my teachers

    Reply
  13. Okebukola Raphael says:
    8 months ago

    Amazing

    Reply
  14. Okebukola Raphael says:
    8 months ago

    Up school

    Reply
  15. Okebukola Raphael says:
    8 months ago

    Good job well done

    Reply
  16. Olaniyi Daniel Kolawole says:
    8 months ago

    Up Afrograms

    Reply
  17. Animaseun Nimotallah Ayomide says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
  18. Aderinwale Misturah omolabake says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
  19. Zato sekinat dele says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  20. Abdulsalam Waliyullahi T. says:
    8 months ago

    Great job

    Reply
  21. Benson Favour Onyenyechi says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  22. Adeyemi Haleem korede says:
    8 months ago

    AWON AKEKO JADE DA AWON AKEKO ATI OLUKO AFRICAN CHURCH GRAMMAR SCHOOL

    Reply
  23. Adeyemi Haleem korede says:
    8 months ago

    Great job🖖

    Reply
  24. RAJIOLA OLUWADARASIMI FOLASHADE says:
    8 months ago

    Up school

    Reply
  25. Tijani Muhammed hadi says:
    8 months ago

    Up school

    Reply
  26. Oyebola Fathia says:
    8 months ago

    Impressive
    Not everything will be in English
    I love this keep it up

    Reply
    • SANUSI AISHAT ENIOLA says:
      8 months ago

      Thank u so much

      Reply
  27. AJAYI HELEN MORUNRAYO says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
  28. Omidiji Haliyat Temitope says:
    8 months ago

    Impressive

    Reply
  29. Akindele Pelumi Elizabeth says:
    8 months ago

    Excellent

    Reply
  30. Dauda Monzidat Omolabake says:
    8 months ago

    Great job
    May God continue to uphold the organisers

    Reply
  31. Ajibola fathia arike says:
    8 months ago

    E ku ise

    Reply
  32. Awesome says:
    8 months ago

    Yusuf kudirat oluwadarasimi

    Reply
  33. Yusuf kudirat oluwadarasimi says:
    8 months ago

    Awesome

    Reply
  34. Oyewole kehinde koriba says:
    8 months ago

    Awesome

    Reply
  35. Ogungbade feranmi Balikis says:
    8 months ago

    Well done

    Reply
  36. OGUNRINOLA MUSTAHIN OLUWAFIKAYOMI says:
    8 months ago

    Good work

    Reply
  37. OBADINA SULiAH OMOWUNMI says:
    8 months ago

    Impressive
    Keep it up sis

    Reply
  38. Sanusi Lateef says:
    8 months ago

    Well done

    Reply
  39. Ochola Lawrence says:
    8 months ago

    Wow!!
    All written in Yoruba
    Beautiful

    Reply
  40. OGANLA SABUUR DAMILARE says:
    8 months ago

    Good work

    Reply
  41. Ojebode oluwadunni says:
    8 months ago

    Impressive

    Reply
  42. Ojebode Oluwadunni says:
    8 months ago

    Wonderful

    Reply
  43. Darasimi Olojede says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  44. Rasheed Furquan says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  45. Darasimi Olojede says:
    8 months ago

    Nice one

    Reply
  46. Mosunmade joy jomiloju says:
    8 months ago

    Impressiveness

    Reply
  47. Kehinde Oluwajuwon esther says:
    8 months ago

    Great job

    Reply
  48. Kazeem yusroh says:
    8 months ago

    Good job

    Reply
  49. HAMZAT WARIS AYOMIDE says:
    8 months ago

    Great job, so wonderful ❤

    Reply
  50. SHOKUNBI SALAM GBEMISOLA says:
    8 months ago

    This is massive

    Reply
  51. Babalola rokeeb korede says:
    8 months ago

    Awesome
    Up school

    Reply
  52. Shojobi Samuel Usman says:
    8 months ago

    This is impressive
    Keep it up

    Reply
  53. Shojobi Samuel Usman says:
    8 months ago

    This is impressive
    Keep it up
    Good job

    Reply
  54. Somuyiwa wasiu Sunday says:
    8 months ago

    You did a very great job
    Please don’t relent

    Reply
  55. Babalola rokeeb korede says:
    8 months ago

    Great work and effort

    Reply
  56. Ogunsina oluwanifemi says:
    8 months ago

    Good job
    Keep it up

    Reply
  57. Akinbode basit oluwapamilerin says:
    8 months ago

    Good work and effort

    Reply
  58. Akinbode basit oluwapamilerin says:
    8 months ago

    Good work and effort

    Reply
  59. Akinbode basit oluwapamilerin says:
    8 months ago

    Good work and effort

    Reply
  60. Akinbode basit oluwapamilerin says:
    8 months ago

    Good work and do not relent

    Reply
  61. Kehinde Oluwatise says:
    8 months ago

    Good job
    More affort in jesus name 🙏🙏🙏🙏🙏🙏

    Reply
  62. Oloyede Oluwafemisola says:
    8 months ago

    WOW.
    More wisdom 🙏🙏🙏

    Reply
  63. Moyinoluwa David says:
    8 months ago

    up school

    Reply
  64. Kabirat Ajoke says:
    4 days ago

    Great and interesting up school. Akinola Ayisat kemi. SSS 1e sir. Steps in writing descriptive composition. 1.ideas 2.use linked expression. 3use of figure of speech 4.make quick outline . 5. understand the topic

    Reply
  65. Kabirat Ajoke says:
    4 days ago

    Great and interesting up school. Akinola Ayisat kemi. SSS 1e sir. Steps in writing descriptive composition. 1.understand the topic. 2.Get ideas. 3.Make a quick outline 4.use linking expression. 5 Use of figures of speech

    Reply

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Recent Posts

  • Mrs Ajayi’s 60th Birthday: A Student of Afrograms Wins A Cash Award of #20,000
  • FIVE STUDENTS OF AFROGRAMS TOP THE LIST IN OLOWU SCHOLARSHIP EXAM
  • Former Principals,Vice Principals,Teachers Honour Mrs Ajayi @ 60
  • (no title)
  • Celebrating Mrs Ajayi At 60

Recent Comments

  1. Yusuf shazali on Goody’s Art and Calligraphy
  2. Yusuf shazali on Goody’s Art and Calligraphy
  3. Akinlabi Elizabeth oluwadarasimi on FIVE STUDENTS OF AFROGRAMS TOP THE LIST IN OLOWU SCHOLARSHIP EXAM
  4. ADELEKE PETER on Celebrating Excellence: Mrs. Ajayi Retires from Ogun State Teaching Service Commission at 60
  5. ADELEKE PETER on Celebrating Excellence: Mrs. Ajayi Retires from Ogun State Teaching Service Commission at 60

About Us

Afronews.ng is the official news platform of the Alumni Association of African Church Grammar School, Abeokuta. Our mission is to empower students, alumni, and the wider academic community by providing a dedicated media space that informs, connects, and inspires.

Facebook-f X-twitter Instagram Youtube

afronews022@gmail.com

Site Menu

  • About
  • Contact
  • Gallery
  • Radio

Top Categories

  • News
  • Academics
  • Alumni Corner
  • Infotech
  • Opinions

© Copyright Powered by Afronews.ng

No Result
View All Result
  • Home
  • News
  • Academics
  • Infotech
  • Entertainment
    • Fashion
    • Sports
  • Personality & Interview
    • Opinions
    • Weekly Insights
  • Advert
  • Afrograms & its community
    • Alumni Corner
    • Features
    • Meetings
    • Plublications
  • Health

© 2025 Afronews - News platform of Afrograms.